Yes, but if you have a sweet fume it can be used.
Write these words at the back of the Invocation: Mo di papa-nla tin jo torun-torun, modi efufu tin mile kikiki; modi kanranjangban inu igbo; eni bani kin ku, awon ni iku kan. Eni bani kin se aisan awon ni aisan kan. Eni ba ro ibi simi ki ibi o ma je tiwon.
Mofun iku ni eyin pepeye je, mo ba iku mule, iku o gbodo pami. Gboin-gboin loke wa! Kin ma ri se niso, kin ma rina, kin ri je, kin ri mu. Ase!"
It’s more like incantation, terrible one. Can’t be written in English. It would strengthen the seal. #Enlightenment